General Knowledge

Kíkún

Absolute

Coined by Hakeem Oluwafemi Adeniyan · June 15, 2022

Definition

Kíkún túmọ̀ sí àpapọ̀, pípé tàbí tí kò ní gbèdéke láti ọwọ́ ohunkóhun. (Absolute means total, complete, or not limited by anything.)

Formation

A sẹ̀dá kíkún nípa ṣíṣe àpètúnpé ọ̀rọ̀-ìṣe kún.

Usage Examples

  • Ìdákẹ́ inú ibùyáwèékà náà jẹ́ kíkún. The silence in the library was absolute.
  • Mo ní ìfọkàntán kíkún nínú àtilèṣe rẹ. I have absolute confidence in your ability.

Cite This Entry

APA 7th Edition

Adeniyan, H. O. (2022, June 15). Kíkún (Absolute). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/kikun/
Adeniyan, H. O. (2022, June 15). Kíkún (Absolute). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/kikun/