Science

Ìwọ̀ngbóná kíkún

Absolute temperature

Coined by Hakeem Oluwafemi Adeniyan · June 15, 2022

Definition

Ìwọ̀ngbóná kikún jẹ́ ìwọ̀ngbóná tí a wọ̀n láti òdo kíkún (−273.15°C tàbí 0 K), níbi tí gbogbo ìṣípò mólékù ti ń dúró. (Absolute temperature is a temperature measured from absolute zero (−273.15°C or 0 K), where all molecular motion stops.)

Formation

A kó àwọn ọmọnú àsọyé yìí jọ láti ara ìwọ̀ngbóná + kíkún.

Usage Examples

  • A máa ń wọn ìwọ̀ngbóná kíkún ní kẹ́lífìn, kì í ṣe ní ipele sẹ́síọ́ọ̀sì. Absolute temperature is measured in kelvins, not degrees Celsius.
  • Sísọ ìwọ̀ngbóná kíkún ẹ̀fúùfù kan di ìlópo méjì máa n sọ òòrìn rẹ̀ náà di ilọ́po méjì. Doubling the absolute temperature of a gas also doubles its pressure.

Related Terms

Cite This Entry

APA 7th Edition

Adeniyan, H. O. (2022, June 15). Ìwọ̀ngbóná kíkún (Absolute temperature). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/iwongbona-kikun/
Adeniyan, H. O. (2022, June 15). Ìwọ̀ngbóná kíkún (Absolute temperature). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/iwongbona-kikun/