Economics

Ìjẹgbárun

Bankruptcy

Coined by Hakeem Oluwafemi Adeniyan · June 9, 2026

Definition

Ìjẹgbárun ni pípàdánù dúkìá ẹni sọ́wọ́ àwọn ayánilówó látàrí àwọn gbèsè tí a kò san. (Bankruptcy is the state of losing property to one’s creditors due to unpaid depts.)

Formation

Ìjẹgbárun = ìjẹ + igbá + run. Igbá jẹ́ dúkìá tàbí ọjà ẹni.

Usage Examples

  • Ìjẹgbárun pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ àtijẹ̀bi rẹ̀ rẹ́, ṣùgbọ́n ó pàdánù ilé rẹ̀. Bankruptcy wiped out most of his liabilities, but he lost his house.
  • Ó rí ìjẹgbárun gẹ́gẹ́ bí ibùsádi ìgbẹ̀yìn láti mórí bọ́ lọ́wọ́ àwọn àjẹẹ́lẹ̀ owó ìtọ́jú. She saw bankruptcy as a last resort to escape medical bills.

Related Terms

Cite This Entry

APA 7th Edition

Adeniyan, H. O. (2026, June 9). Ìjẹgbárun (Bankruptcy). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/ijegbarun/
Adeniyan, H. O. (2026, June 9). Ìjẹgbárun (Bankruptcy). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/ijegbarun/