General Knowledge
Àtilèṣe
Ability
Definition
Àtilèṣe túmọ̀ sí níní agbára, ìmọ̀ọ́ṣe, tàbí ọ̀nà láti sẹ nǹkan. (Ability means having the power, skill, or means to do something.)
Formation
A ṣẹ̀dá àtilèṣe láti ara àti+lè+ṣe.
Usage Examples
- Àyẹ̀wò-ráńpẹ́ náà wọn àtilèṣe rẹ nínú ìmọ̀-ìṣirò. The test measures your mathematical ability.
- Ó ní àtilèṣe àdámọ́ láti mú kí awọn ènìyàn ní ìmọ̀lára ìdẹ̀kùn. He has the natural ability to make people feel comfortable.
Cite This Entry
APA 7th Edition
Adeniyan, H. O. (2023, June 15). Àtilèṣe (Ability). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/atilese/
Adeniyan, H. O. (2023, June 15). Àtilèṣe (Ability). In Yoruba Terminology Dictionary. Retrieved from https://hakeemoadeniyan.github.io/dictionary/atilese/